Русские видео

Сейчас в тренде

Иностранные видео


Скачать с ютуб Odi meji odu agba в хорошем качестве

Odi meji odu agba Трансляция закончилась 3 года назад


Если кнопки скачивания не загрузились НАЖМИТЕ ЗДЕСЬ или обновите страницу
Если возникают проблемы со скачиванием, пожалуйста напишите в поддержку по адресу внизу страницы.
Спасибо за использование сервиса savevideohd.ru



Odi meji odu agba

Kóróbótó kóróbótó ni wóón pilè àwợn Bó bá dókè a gbibú A móợ gbợmợrí odó A móợ gbợmợrí ợlợ A dífá fún Àkèsán Àkèsán tíí şe baálè ợjà olówó Àkèsán lợjà àkódá ńlé ayé Ợba ló si ni í Obìnrin sí ni Ợba òhún Wón ní kó rúbợ Ó bá rúbợ Ó rú ohun gbogbo nígbà nígbà Gbogbo ayé bá Àkèsán pé Tée dòní ní wón ń nájà Àkèsán Gbogbo ợjà tó kù ti wón dá Àkèsán ní bàbá gbogboo wợn Ifá pé ayé ó yẹ ẹni ó dá Ifá yìí Ó tóbi tán ní ń yin Ifá Ifá ń yin Olódùmarè Ợba Ó ní béè làwợn Babaláwo tòún wí Kóróbótó kóróbótó ni wóón pilè àwợn Bó bá dókè a gbibú A móợ gbợmợrí odó A móợ gbợmợrí ợlợ A dífá fún Àkèsán baálè Ợjà Olówó Wón ní ó rúbợ kó lè baà tóbi Kó lè baà dẹni ńlá láyé Àkèsán gbébợ ńbè Ó rúbợ Írú ẹbợ Èèrù àtùkèsù Ệ wáá bá ni ní jèbútú ire Jèbútú ire làá bá ni lésè Ợba Òrìşà Àkèsán mòmò dé ò Báàlè ợjà Báa bá rólórí rere À á dájà. whatsapp 2199808-2674

Comments